Awon Oba alaye ile Yoruba, eleyii ti Ooni ile ife, Alayeluwa Oba Okunade Sijuwade kosodi ti pawopo fi opa ase isembaye sure fun Aare Jonathan lonii ni ile Ife lati bori ninu eto idibo to n bo.
Sugbon sa, Alaafin ti ilu Oyo, Lamidi Olayiwola Adeyemi III ko si ninu awon oba naa.
#rere run o!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment