Omidan Sahhara ni yii, omo Nigeria nii se. Okunrin ni awon obi omo naa bi saye. Sugbon igba to dagba tan lo ni obirin lo wu ki oun jẹ. Ilu Biritiko ni won ti ba pari ise na, ti gbogbo ala rẹ si wa si imusẹ. Ilu London ni Sahhara n gbe ba yii. E le ka si nipa re ninu awon akole iroyin to wa nisale yii.
Home / Amuludun /
Foto /
Iroyin Okeere
/ Omokunrin To Yirapada Di Omoge Ti Gbara Mi Yo: Ara Orisirisi Lowo Sahhara
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment