"Won doyii kapa, apa o kapa, won dooyi ka konga ko see kosi" Gbolohun ti awon omo egbe APC kan fi dahun ibeere niyii nikete ti Mummadu Buhari to je oludije fun ipo Aare labe egbe oselu APC sokale ninu baalu pelu ogooro awon oniroyin ti won ti n duro dee lati fi oro wa lenu wo. Lara afikun atejade egbe APC ni wi pe, ipadawale Buhari, ibanuje nla ni fun Aare Jona oko Patience.
Home / Foto /
Oro Oselu
/ [Foto] Buhari Ti Pada Silu Nigeria: "Ibanuje Ti De Ba Aare Joinathan" Awon APC Lo So Bee
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment