Happy Birthday Oluwafemi Oladele - Femi Solar ( King of Jasa Music Olayemi Oniroyin 8/05/2016 12:00:00 am Add Comment Edit E fi efun pale laro. E pagbo orin idunnu, E mu ikoko obe to jin koto ke e fi gbesu kana. Bisu bajina tan, e kosu sinu odo ke e gunye ire... Read More
Omo Fela fi abuku kan Ooni Enitan Adeyeye Ogunwusi Olayemi Oniroyin 8/03/2016 10:28:00 pm Add Comment Edit Seun Kuti Seun Kuti, okan ninu awon omo oloogbe Fela Anikulapo-kuti ti naka aleebu si Ooni Ogunwusi nipa bi oba alaso funfun naa se ni... Read More
Epe ti Tee Bliz se fun Tiwa Savage dabi omi ta da seyin lara Olayemi Oniroyin 8/03/2016 04:24:00 pm Add Comment Edit Tiwa: Ibadi mi ki sibe Bi o tile je wi pe enikeni ko gbo ohunkohun mo nipa oko Tiwa Savage to ko sile, sugbon ohun to daju ni wi pe,... Read More
Ohun ti Seun Egbegbe tun so nipa Toyin Aimakhu ni yii Olayemi Oniroyin 8/02/2016 04:27:00 pm Add Comment Edit Kosi oun ti ko le sele laye yii sha. Nje eyin le biliifu wi pe Seun Egbegbe, maanu to fe Toyin Aimakhu leyin ti Adeniyi Johnson ko sile, e... Read More
Olayemi Oniroyin gbe ara mii yo:Ogbamugbamu Olayemi Oniroyin 7/23/2016 01:30:00 pm Add Comment Edit Mi o tile le ranti odun ti mo rkoodu eto yii, sugbon mo lero wi pe e o gbadun re gidi gan-an. Inu mi yoo si dun lati ri esi gba lati odo... Read More