Àìmọye àwọn ènìyàn ní wón ti ń ranse ibanikedun sì Olamide Baddo pelu bo se pàdánù ìyá rẹ logbon ojo oṣù kinni odun 2018. Ọjọ yìí kan náà ni...
Read More
Home / Amuludun
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Olajumoke ọmọ oniburedi sì ń migboro titi
Olajumoke Orisaguna tí gbogbo ènìyàn mo sì Olajumoke ọmọ oniburedi sì ń jẹun lọ nígboro pelu àwọn ipolowo orisirisi eléyìí to ń ṣe fún àwọn ...
Read More
Ọmọge onídòdò tí patẹ ọjà fáyé
Ìṣe aṣẹ́wó kii se ohun ìtìjú mọ báyìí. Àwọn tí wọn ṣe gba a gẹ́gẹ́ bí ìṣe ajé ni, lára ohun tí olaju mú wọlé nù un. Ọkàn nínú àwọn ọmọge Lek...
Read More

Ọdún mẹ́tàlá ni mo fi jókòó sile kí n tó rí Yunifásítì wọ - Muyiwa Ademola
"Wọn kò bí mi sílè ọlá. Baba mi kò ní kẹ̀kẹ́ débi wí pé yóò ra motor. Inú irà ni wọn bí mi sì nílùú Ibadan, níbi tí kò ti sina elentiri...
Read More
Edua tí bù kún mi kọjá òye mi- Muyiwa Ademola
"Èdùmàrè mo dúpẹ́, nítorí ó bu kún mi kọjá òye mi. Mo ti bá ọba jẹun, mo sì ti bá ìjòyè jókòó tayo alọpọn. Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Edua Òkè tó ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)