Yorùbá Ni Tòótọ́: Yorùbá kò ní pẹ tán tí a kò bá mọ nípa ìtàn wa Olayemi Oniroyin 4/01/2018 03:53:00 pm Add Comment Edit Mensa Otabil, olùkọ́ni , onkọ̀wé , olokoowo ńlá, àti ẹni àkọ́kọ́ ti yóò ṣe idasilẹ Yunifásítì aladani ni orileede Ghana sọ wí pé, "àwọn... Read More
Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jagun Asa Olayemi Oniroyin 3/31/2018 07:30:00 am Add Comment Edit Won ni bí a kò ba rí ẹyẹ igun a gbọ́dọ̀ ṣebọ, bí a kò rí ẹyẹ akala a gbọdọ sorò, bí a kò bá ti rí ewé akòko kò sí bá a ti fẹ́ joyè nílẹ̀ yìí... Read More
Ọjọ́ kẹwàá ni Timi Ẹdẹ ṣe ọdún kẹwàá lórí oyè. Gọngọ sọ! Olayemi Oniroyin 3/11/2018 03:26:00 pm Add Comment Edit Ilu Ede ò gbèrò lánàá, ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2018, nígbà tí Ọba Munirudeen Adesola Lawal, Timi tiluu Ede ṣe ayẹyẹ ọdun kẹwàá lórí oyè. À... Read More
Olori Memunat tí bí ìbejì láàfin Ọba Adeyemi Lamidi Olayemi Oniroyin 2/25/2018 12:23:00 pm Add Comment Edit Ìdùnnú tí ṣubú layo láàfin Ọba Adeyemi Lamidi, Aláàfin ilu Ọ̀yọ́, pelu bí olórí kékeré, Memunat, ṣe bí ìbejì fún Ikú Babayeye Read More
Aje World Festival 2018: Àwọn foto láti ibi Ọdún Aje to wáyé ní Ilé Ìfẹ́ Olayemi Oniroyin 2/22/2018 12:09:00 pm Add Comment Edit Ẹsẹ ko gbero lọjọ Aje to kọjá yìí ni ilé Ìfẹ́ nibi ti Ọdún Aje 2018 tí gbé wáyé. Read More