E wa wo ohun ti won se soju JJ Okocha agbaboolu Olayemi Oniroyin 9/24/2016 11:37:00 am Add Comment Edit Ise owo 'Hakeemeffect' ni, asarologe ti n se wondeful. O so oju JJ Okocha di baba arugbo. Oju agbalagba ti won se fun ... Read More
Cristiano Ronaldo tun ti gba gbogbo irawo agbaboolu to dara ju lo ti Europe patapata Olayemi Oniroyin 8/26/2016 09:52:00 am Add Comment Edit Cristiano Ronaldo O wu Edumare lo sori ewa fakuko. Sebi won ba Oya ja lasan ni, Sango lo ni seere. won ti gbe ami eye agbaboolu to da... Read More
Asiri ohun ti Cristiano Ronaldo n se to fi derujẹjẹ ni yii Olayemi Oniroyin 8/19/2016 10:33:00 pm Add Comment Edit Gege bi alaye awon onwoye, ati doke ko nira bi ati duro soke nigba gbogbo. Aimoye awon eniyan ni won simi sara latari okiki ati iyi... Read More
Nigeria fakoyo! Won na Japan sare kabakaba ni Rio Olympics Olayemi Oniroyin 8/05/2016 05:51:00 am Add Comment Edit Ninu idije ere boolu alafesegba ti Rio Olympics, abala ti awon okunrin, egbe agbaboolu Naijiria, ti jawe olubori ninu ifesewonse akoko wo... Read More
Apeere wi pe Naijiria ni yoo gba goolu labala boolu alafesegba ni Rio Olympics Olayemi Oniroyin 8/04/2016 05:19:00 pm Add Comment Edit Nje eyin gbagbo? Read More