[Foto] Gbajumo ni Mide Funmi Martins lojokojo Olayemi Oniroyin 8/19/2016 09:56:00 pm Add Comment Edit Mide Funmi Martins, okan ninu awon osere sinima Nollywood ile Nigeria ni gbajumo wa lose yii. Funmi je aya Afeez Owo ti oun naa je ... Read More
Agbeyewo ojulowo ise iroyin to pegede Olayemi Oniroyin 8/18/2016 10:47:00 pm Add Comment Edit Adewale Dada Thegood Akurẹtẹ ti deba isẹ iroyin eleyii to mu pupo ninu awon koko ti ise iroyin dálé di ohun igbagbe. Eleyii ... Read More
Ayo Adesanya: E wa woju omo olojo-ibi bo se n dan bi ide Olayemi Oniroyin 8/13/2016 03:00:00 pm Add Comment Edit Ayo Adesanya, ogbontarigi osere onitiata ile Naijiria, le lodun ni ijeta, [11-08-16]. Sugbon bayii, omobirin naa ti n se afihan gbogbo fa... Read More
Happy Birthday Oluwafemi Oladele - Femi Solar ( King of Jasa Music Olayemi Oniroyin 8/05/2016 12:00:00 am Add Comment Edit E fi efun pale laro. E pagbo orin idunnu, E mu ikoko obe to jin koto ke e fi gbesu kana. Bisu bajina tan, e kosu sinu odo ke e gunye ire... Read More
E wa woju ojulowo omo Yoruba: Olori Ademidun Adetoro Fagbenro gbayi! Olayemi Oniroyin 8/04/2016 09:03:00 am Add Comment Edit Oni ni ojo ibi Olori Ademidun Adetoro Fagbenro, ojulowo omo Yoruba to yaayi to tun logbon lori ni, orekelewa obirin ti ki i rinrin ido... Read More