Niwon igba to je wi pe gbogbo eni ti n korin ko ni won korin gidi, bakan naa, a le gba wi pe gbogbo onise tiata ko nise opolo won kun fo...
Read More
Home / Gbajumo Lawujo
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
![[Audio] Ohun ti Wale Dada se ni yii lojo to reni to fe ga soke [Audio] Ohun ti Wale Dada se ni yii lojo to reni to fe ga soke](https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEh_dUDC66dIjI4He0CsE-IsioyyIe9p7lZ2VERJO92aVg4IpXoxL841BhR2Zv9hGOwq6PWsS4NXHisxa2rcXZkFZQkn-SRhjQBXwymOsU0KDbpxsyEWkBcQrBC0ZU81eKLpFTWqlOUt5Nc/w300-h190-c/283085_2067759726282_5578652_n.jpg)
[Audio] Ohun ti Wale Dada se ni yii lojo to reni to fe ga soke
Adewale Dada Thegood Ile aye yii ile asan ni, E je ki agbe ile aye se rere . Ohun ti a gbese ni koro ma foju han sita lojo kan. Asepam...
Read More

Ifẹ aladun Anuoluwapo pelu Ibironke dun bi oyin
Bi ere bi awada nifẹ Anuoluwapo ati Ibironke bẹrẹ Sugbon Edumare foyin si i, adun si wọ igbe aye awon mejeeji. Lonii ọjọ kerindinlọgbọn ...
Read More

Iba oga oniroyin: Chris Kehinde Nwandu @ 50
Chris Kehinde Nwandu O wu gbogbo eye ki won lola bi eye okin, aso aran ni won o ni nile. O wu eye aparo ko ba lekeleke dogba, ailaso ...
Read More
![Awon ise iyanu Olamide Ogunade [Olisco] ni yii Awon ise iyanu Olamide Ogunade [Olisco] ni yii](https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEizMwlXrV88sLzG68P8-g2DI_sJcYl1E4DiCL7B2lIyMgHZ7zjvvNdgJlcDAab1_3bzNrL0ISIbBQLJdYJNU4DrtN2pSKISyeqtPjc4YwmdwumvcJxPQHn5RrapdKwFQiG6pJMEqOtU41Q/w300-h190-c/Snapshot%252846%2529.png)
Awon ise iyanu Olamide Ogunade [Olisco] ni yii
Aimoye odo ile yii lo logbon lori ti won si lebun to fakiki. Okan ninu won ni Olamide Ogunade ti gbogbo eniyan mo si Olisco. Awon ise iy...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)