Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo Olayemi Oniroyin 11/22/2015 10:15:00 am Add Comment Edit 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun ... Read More
Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin Olayemi Oniroyin 11/16/2015 05:43:00 pm Add Comment Edit Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun... Read More
Ohun te e ma se ti e ba fe ki irun yin gun daada Olayemi Oniroyin 11/15/2015 05:22:00 pm Add Comment Edit Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu... Read More
ILERA LORO: Bi a se le se itoju ehin enu wa Olayemi Oniroyin 10/17/2015 07:17:00 pm Add Comment Edit #Oniroyin @OlayemiOniroyin Aridaju iwadii ti fi ye wa wi pe osan orombo dara pupo ni mimu eleyii to n fun erigi ehin wa ni agbara. ... Read More
Ewe ati Egbo Ile Yoruba 3: OOGUN OGBE INU TO DAJU Olayemi Oniroyin 8/31/2015 07:43:00 am Add Comment Edit A o wa Ogede agbagba to po die, a o bo eepo ara re kuro. Leyin eyi ni a o ge wewe sinu abo nla kan pelu omi to po die ninu. Read More