Idi Omoge Onidodo Fọ Nibi O Ti N Se Kerewa Olayemi Oniroyin 3/22/2015 06:15:00 pm Add Comment Edit Eni ba yo tan ti n wa bekunbekun kiri lọrọ awon ọlọmọge ti won gbe ike sinu idi ki idi won le ranju bọnbọn labẹ aso. Read More
Ohun Abami Farahan Loju Orun Ni Ilu United Kingdom: Ohun Abami Naa Fe Jo Oju Eniyan Olayemi Oniroyin 3/22/2015 06:09:00 pm Add Comment Edit Ninu ọsẹ to koja yii ni ọsan-doru sẹlẹ ni ilu United Kingdom. Arabirin Gemma, eni ogoji odun (40) to n gbe ni Newcastle ya awon foto kan ... Read More
E WA Wo Omoge Ti N Ri Ihoho Kiri Ilu New York Olayemi Oniroyin 3/22/2015 06:08:00 pm Add Comment Edit Erica Simone, to je onise-ọna ayaworan lo ti bẹrẹ si ni se akojopo awon foto rẹ eleyii to n ya ni ihoho kiri ilu New York bayii. Won ni o... Read More
Foto Nicki Minaj Lode Orin Olayemi Oniroyin 3/20/2015 11:39:00 pm Add Comment Edit Won ni ilu Amerika, imura wa lara ohun to mu awon olorin di won gbajugbaja eleyii ti won fi n pawo bi baba ijebu. Pupo imura aso won ni ki... Read More
Omo Sun Baba Ati Iya Re Je Bi Suya Ni Ilu Hong Kong Olayemi Oniroyin 3/20/2015 11:33:00 pm Add Comment Edit Bi eniyan ba n toro omo ki eniyan toro iru omo to n fe gan-an. Iroyin agbaye ti gbe Henry Chau Hoi-leung, omo ilu Hong Kong to fi baba ... Read More