Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko Olayemi Oniroyin 12/30/2015 05:22:00 pm Add Comment Edit Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye lat... Read More
Ogo ati ola ilu Mecca ati Medina ni orileede Saudi Arabia Olayemi Oniroyin 12/24/2015 09:03:00 pm Add Comment Edit Ogo ati ola ilu Mecca ati Medina ni orileede Saudi Arabia Read More
Alaboyun bimo soju titi lonii niluu China Olayemi Oniroyin 12/16/2015 06:36:00 pm Add Comment Edit Arabirin oloyun yii lomo bere si ni mu lonii nigboro ilu China. Awon eniyan ti won lo ni won sare se iranlowo fun un. Won pe obirin noosi... Read More
Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa Olayemi Oniroyin 12/12/2015 12:34:00 pm Add Comment Edit Gege bi oro awon Yooba,"eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae." Okunrin kan to pe ara re ni... Read More
Gobe sele lagbo Davido Olayemi Oniroyin 12/12/2015 12:27:00 pm Add Comment Edit Orisiirisii ara ni awon omo olorin igbalode maa n da lagbo ere orin. Iru ara bee ni bi ki won bo aso lorun ki won si ju si aari... Read More