Orí ènìyàn ni won ka mọ Babalola lọ́wọ́ nipinle Ogun Olayemi Oniroyin 2/02/2018 08:43:00 am Add Comment Edit Àwọn olopaa ìpínlẹ̀ Ogun tí mú ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ ń jẹ Babalola Alex (25yrs) pelu bí wọn ṣe ká orí ènìyàn mọ ọ lọ́wọ́ ni agbegbe Asese.... Read More
Haaaa! hehehehe ohun tí ọmọge náà rò kọ lo ba Olayemi Oniroyin 2/02/2018 08:03:00 am Add Comment Edit 😂 😂 😂 Read More
Àṣírí ara Miami tú pátápátá Olayemi Oniroyin 2/02/2018 07:55:00 am Add Comment Edit Gbajuẹ! Ó ní òun wà létí omi odo Miami jaye bí Ọba Lamidi. Bí ó bá tilẹ parọ wí pé òun wà létí odò Ogunpa nIbadan ṣebi a bá darijin. Werey ... Read More
Ìdájọ́ ọmọbìnrin to fẹ gbé ẹyẹ ọkin wọnú baalu nílùú America Olayemi Oniroyin 2/01/2018 07:20:00 pm Add Comment Edit Arábìnrin kan tó fẹ́ tirafu pelu ẹyẹ ọkin ni wọn ti dapada nígbà tó kú kò gbese wọnú baalu ni orileede America 🇺🇸. ... Read More
Oyun méjìdínlógún (18) lọ bajẹ lára mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ si ni fẹ Gani Adams - Mojisola Adams Olayemi Oniroyin 2/01/2018 05:34:00 pm Add Comment Edit "Lónìí, adùn ni ṣùgbọ́n mo ti fi ìgbà kan wá nínú ibanuje ri. Oyún bí méjìdínlógún (18) lọ bajẹ lára mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ pelu ọkọ mi,... Read More