Ṣé gómìnà bí Ambode wá nilẹ Yorùbá? Olayemi Oniroyin 3/29/2018 11:34:00 pm Add Comment Edit Ká má parọ, ibùdókọ̀ yìí rẹwà gidi gan-an. Kosi ìyàtò láàárín rẹ atí àwọn ìlú tó ti gòkè àgbà lagbaye. Ó kàn je wí pé karamọ àti ayẹyẹ tí wọ... Read More
Ohun tó mú Ibile 9ja Radio yàtọ̀ gédégédé ni yìí Olayemi Oniroyin 3/23/2018 09:18:00 am Add Comment Edit Lára àwọn ileese rẹdio orí ayélujára tí ń lewaju lákòókò yìí ni Ibile 9ja Radio, eléyìí tí òkìkí rẹ ń lọ sókè sí i láti ìgbà tí wọn ti bẹ̀r... Read More
Ẹ wá ohun tí abarapá abiyamọ ń ṣe lojoojumo Olayemi Oniroyin 3/23/2018 08:57:00 am Add Comment Edit Ìbéèrè tó kọ́kọ́ wá sí mi lọ́kàn ni wí pé níbo jí ọkọ obìnrin náà wá? Read More
Lẹ́yìn ikú Ishola Oyenusi, ògbólógbòó adigunjale, ohun ti ìwé ìròyìn sọ lodun 1973 ni yii Olayemi Oniroyin 3/21/2018 08:20:00 pm Add Comment Edit Gẹ́gẹ́ bí ìwé ìròyìn Daily Times ọdún 1973 ṣe sọ. Lèyín ikú ògbólógbòó adigunjale, Ishola Oyenusi, ọlọ́wọ́ ọtun rẹ, Mighty Joe, pitu méje tí... Read More
Muyiwa Ademola tí padà sí kíláàsì gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ Olayemi Oniroyin 3/16/2018 03:37:00 am Add Comment Edit Kosi bí ènìyàn tí wù kó lọ́gbọ́n tàbí ní imọ, tí ẹnì náà kò ba ni ifarabalẹ, yóò nira fún irú ẹni bẹẹ láti sọ alaimọkan di onímò kíkún. Yàt... Read More