Igbo Sambisa: Ohun tí àwọn sójà ń ṣe lojo àjíǹde ni yìí Olayemi Oniroyin 4/02/2018 01:47:00 pm Add Comment Edit Láàárín àwọn ọ̀tá, níbi tí ota ìbọn tí ń fò bí ẹyẹ ojú ọ̀run, nínú igbó aginjù Sambisa, àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà péjọ pọ̀ fún ìsìn àjíǹde. Wọ... Read More
Ọmọbìnrin to bọ lọ́wọ́ cancer tí gbé ìgbà ọpẹ Olayemi Oniroyin 4/02/2018 10:18:00 am Add Comment Edit "Ni iru àkókò yìí lodun tó kọjá, mo sebi ohun tó kàn fún mi ní ikú. Ṣùgbọ́n ikú kò wù mú kú. Ara ń ní mi, àìsàn jẹjẹrẹ kò jẹ ń gbádùn, ... Read More
Original ọmọ àlè ni Oluwo tí Ilu Iwo- Femi Fani Kayode lọ sọ bẹẹ Olayemi Oniroyin 4/01/2018 09:14:00 pm Add Comment Edit Femi Fani Kayode to kan Ọba Abdulrasheed Akanbi lábùkù látàrí bo se sọ ara di Emir Osan gangan Read More
Ìyàwó alarede gun ẹṣin funfun wọ sọọsi Olayemi Oniroyin 4/01/2018 04:30:00 pm Add Comment Edit Ni Tudun Wada to wá nílùú Jos, ìyàwó alarede gun ẹṣin funfun wọ sọọsi. Gbogbo àwọn ènìyàn ń juwọ sìi lọtún losi, bẹ́ẹ̀ ni òun náà bóyín sí w... Read More
April fool: Àwọn olopaa Naija rí owó tabua tí lólúwa Olayemi Oniroyin 4/01/2018 12:09:00 pm Add Comment Edit Read More