Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye Olayemi Oniroyin 11/20/2015 04:28:00 pm Add Comment Edit Oloye Omowale Kuye Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye len... Read More
Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon Olayemi Oniroyin 10/28/2015 10:39:00 pm Add Comment Edit Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii Read More
Won ti gbe oye Dokita fun Oba Lamidi Adeyemi III Olayemi Oniroyin 10/24/2015 04:35:00 pm Add Comment Edit Oba Lamidi Adeyemi III Leyin ayeye ojo ibi odun metadinlogorin (77) Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III to waye laipe yii, awon... Read More
Ayeye Ojo Ibi Oba Lamidi Olayemi Oniroyin 10/19/2015 10:06:00 am Add Comment Edit Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Read More
Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72) Olayemi Oniroyin 9/19/2015 08:00:00 am Add Comment Edit Olatunbosun Oladapo Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba ... Read More