ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:42:00 pm Add Comment Edit ORÚKỌ ÀWỌN ALÁÀFIN Ọ̀YỌ́ TO TÍ JẸ ṢÁÁJÚ KÒ TO WA KAN ALÁÀFIN ÀSÌKÒ YÌÍ 1 - Oranmiyan 2 - Ajaka 3 - Shango 4 - Aganju 5 - Kori 6 - Olu... Read More
Lára ohun tó mú Yorùbá yàtò gedegbe ni yìí Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:36:00 pm Add Comment Edit Yorùbá kìí rìn ìrìn ìdọ̀tí. Yorùbá kìí wọ akisa. Yorùbá lónìí ká wọ buba, ká wọ ṣòkòtò, ká wá gbé agbádá le e lórí. Yorùbá lo ní ká rí ẹni,... Read More
Oluwo tí ilu Iwo ti padà pelu ara tuntun Olayemi Oniroyin 4/04/2018 10:26:00 pm Add Comment Edit Oluwo tí Ìwọ , Oba Abdul Rasheed Akanbi tún gbéyo pelu ara tuntun nígbà tó dáṣẹ̀ jade láàfin rẹ pẹlu aṣọ onisokoto tiirin. Tí ẹ kò bá gbàgb... Read More
Yorùbá Ni Tòótọ́: Yorùbá kò ní pẹ tán tí a kò bá mọ nípa ìtàn wa Olayemi Oniroyin 4/01/2018 03:53:00 pm Add Comment Edit Mensa Otabil, olùkọ́ni , onkọ̀wé , olokoowo ńlá, àti ẹni àkọ́kọ́ ti yóò ṣe idasilẹ Yunifásítì aladani ni orileede Ghana sọ wí pé, "àwọn... Read More
Lọ́jọ́ tí wọn fi Femi Branch jẹ Jagun Asa Olayemi Oniroyin 3/31/2018 07:30:00 am Add Comment Edit Won ni bí a kò ba rí ẹyẹ igun a gbọ́dọ̀ ṣebọ, bí a kò rí ẹyẹ akala a gbọdọ sorò, bí a kò bá ti rí ewé akòko kò sí bá a ti fẹ́ joyè nílẹ̀ yìí... Read More