Home / Isese Yoruba
Showing posts with label Isese Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Isese Yoruba. Show all posts

Saheed Osupa kọrin fún àwọn Igbarumole
Saheed Osupa kọrin níbi ọdún Isese eléyìí to wáyé loke MAPO, Ibadan, 21-01-2018. Àkòrí ọdún náà ni IGBARUMOLE eléyìí tí Erelu Amope Olorisha...
Read More

Oríkì Ilu Ede: Ó ti pe ọdún mẹ́wàá báyìí tí Ọba Muniru Adesola tí gorí ìtẹ́
Oríkì Ede Ede màpó arógun, Iyako agbo Èyin Ọmọ ají lala ọsọ Ọmọ ají sọsọ Ọmọ ají f'ọjọ́ gbogbo dára bí egbin, Ede ọmọ elepo rédé, ...
Read More
Ìsìn idupe Ààrẹ Ọna Kakanfo ni Soosi
Gani Adams àti Aláàfin Ọ̀yọ́ kasẹ eto gbogbo nílé bí ní ile ìjọsìn láti fi ọpẹ fún Olúwa nipa ayẹyẹ Ààrẹ Ona Kakanfo to waye
Read More
Oríkì Oyo: Aláàfin Lamidi Olayiwola Adeyemi
A ki rọ’ ba fin la lẹ de Ọyọ O ya ẹ jẹ a lọ ree ki Alaafin Olayiwola ọmọ Adeyemi ọkọ Abibatu. Lamidi ọmọ a jowu yọ kọ lẹnu A bi Ila tọ-tọ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)