Aare Buhari n bọ nipinlẹ Eko lọjọ Monde Olayemi Oniroyin 5/21/2016 02:45:00 pm Add Comment Edit Aare Buhari n bo nipinle Eko fun igba akoko leyin to ti wole gege bi Aare ni nnkan bi odun kan seyin. Ile ise ijoba ipinle Eko ti gbe at... Read More
Ko sowo lapo Naijiria- Lai Muhammed Olayemi Oniroyin 5/19/2016 09:58:00 pm Add Comment Edit Minisita fun etigbọ ati asa, Lai Muhammed, ti so wi pe, isoro ti n koju Naijiria gan-an ni isoro ailowo lowo. Oro yii lo so nikete ti wo... Read More
Musiliu Obanikoro kawe gboye ni Atlanta to wa ni Amerika Olayemi Oniroyin 5/16/2016 08:18:00 pm Add Comment Edit Musiliu Obanikoro, igbakeji minisita fun eto abo abele nigba kan ri kawe gboye (B.Sc in History) ni ileewe Oglethorpe University to wa n... Read More
Yemi Osinbajo ti salaye idi ti ijoba fi fowo kun owo epo robi Olayemi Oniroyin 5/14/2016 12:02:00 am Add Comment Edit Igbakeji AareYemi Osinbajo Atejade tuntun ti jade lati ofiisi igbakeji aare, Yemi Osinbajo, nipa bi ijoba se fi owo kun owo epo robi. I... Read More
Doyin Okupe ti lo dọbalẹ gbalaja niwaju Ẹbọra ilu Owu Olayemi Oniroyin 5/13/2016 11:36:00 pm Add Comment Edit Enu ti igbin fi bu orisa, o ti pada lo fi ẹnu naa gbolẹ. Amugbalegbe nipa eto iroyin fun Goodluck Jonathan nigba isejoba re, Doyin Okupe... Read More