Wunmi ku nipinle Ondo nigba to fe seyun Olayemi Oniroyin 12/12/2015 07:30:00 pm Add Comment Edit *Owo babalawo lo ti gba oogun oyun sise naa Wunmi Agbeluyi Bi o ti wu ki eniyan daju bi ose to, ti eni naa ba ribi ti Wunmi Agb... Read More
Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa Olayemi Oniroyin 12/12/2015 12:34:00 pm Add Comment Edit Gege bi oro awon Yooba,"eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae." Okunrin kan to pe ara re ni... Read More
Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu? Olayemi Oniroyin 11/25/2015 07:50:00 pm Add Comment Edit Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon i... Read More
#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere Olayemi Oniroyin 11/07/2015 07:26:00 pm Add Comment Edit #Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere Olayemi Olatilewa Lojo Wesde to koja yii nile igbimo... Read More
Orisiirisii la n ri nibi eto igbeyawo aye ode oni Olayemi Oniroyin 10/25/2015 08:07:00 pm Add Comment Edit Se ara eto igbeyawo ile Yoruba naa ni yii? Oko kawo le aya iyawo re nigba ti iyawo naa kawo le ori (re mi) ololufe re nita gbangba. Se ... Read More