Ayeye odun marunlelogoji lori oye: Alaafin Oyo gbarada! Olayemi Oniroyin 1/17/2016 05:00:00 pm Add Comment Edit *Oba Lamidi sodun ola, asa ati ewa ile Yoruba *Aimoye ero repete lojude Alaafin Oyo *Akewi ni Alaafin rekoja igbakeji Orisa I... Read More
IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo Olayemi Oniroyin 12/27/2015 07:03:00 pm Add Comment Edit Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira... Read More
E wa wo ohun ti Ooni tun se nile ijosin Olayemi Oniroyin 12/16/2015 06:49:00 pm Add Comment Edit Ooni tuntun ti lo fori bale niwaju Olorun oga ogo nile ijosin. Awon kan ri gege bi ohun to ye fun eni to mo Olorun sugbon awon kan ri g... Read More
Awon eniyan seranti ise Tunde Kelani Olayemi Oniroyin 12/15/2015 06:44:00 pm Add Comment Edit O daju wi pe awon eniyan ko le gbagbe awon ise ti Tunde Kelani ti se. Ko ni i se pelu iye odun to ti se awon ise naa seyin, titi lailai n... Read More
Wunmi ku nipinle Ondo nigba to fe seyun Olayemi Oniroyin 12/12/2015 07:30:00 pm Add Comment Edit *Owo babalawo lo ti gba oogun oyun sise naa Wunmi Agbeluyi Bi o ti wu ki eniyan daju bi ose to, ti eni naa ba ribi ti Wunmi Agb... Read More