[Foto] Ijaya Leru Aya Mi- Dayo Amusa Olayemi Oniroyin 8/05/2015 12:42:00 pm Add Comment Edit Ti omo eni ba dara ka wi, ka maa puro Dayo Amusa leku. Atinu atode, gbogbo re lo pon winnikeke bi moinmoin olororo to kun fun opolopo ... Read More
Aye Akamara: Kini Tajudeen Azeez Fe Fi Kidirin Ati Ifun Omo Odun Merin To Pa Se? (E sora, aworan abanilokan je wa nibi) Olayemi Oniroyin 7/28/2015 10:24:00 am Add Comment Edit Tajudeen Azeez omo odun merindinlogun(16) ni owo awon olopa ti te pelu bo se seku pa Ibrahim, omo odun merin (4) kan ni agbegbe Ijanik... Read More
Morufa Eko 6: Oko Anti Mi Wa Ka Mi Mo Yara Mi Laago Kan Oru Lojo Ti Ko Si Anti Mi Nile Olayemi Oniroyin 7/18/2015 02:52:00 pm Add Comment Edit Morufa Eko ti fi leta eleekafa re ranse, eyi si dun mo wa ninu pupo. Fun anfaani eyin ti e ko mo ibi ti a ba de ati eyin ti ko mo ibi ti... Read More
Odun Ipese Ounje Obo Ni Ilu Thailand Olayemi Oniroyin 7/16/2015 09:00:00 am Add Comment Edit Odun ajobo lodun Ipese Ounje Obo ni ilu Thailand eleyii to ma n waye ni Ipinle Lopburi to wa ni apa ariwa olu ilu Thailand, Bangkok. ... Read More
"Awon Pasito ati Lemoomu Ma N Yo Wa Ye Ifa Wo Lowo Mi" - Ifayemi Elebuibon Olayemi Oniroyin 7/13/2015 09:30:00 am Add Comment Edit Ojo aboki tipe ni Sabo. Ti a ba n so nipa sowo-sesegun, ogboju babalawo to daju ni Araba Ifayemi Elebuibon. Oun gan-an ni a ba maa... Read More