Smiley face
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita

Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita

Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je.
Read More
Radio Biafra Ti Pada Senu Ise: Se Kii Se Wi Pe Awon Omo Yibo Fe Da Ogun Biafra Mi-in Sile?

Radio Biafra Ti Pada Senu Ise: Se Kii Se Wi Pe Awon Omo Yibo Fe Da Ogun Biafra Mi-in Sile?

Ile ise Radio Biafra ti ikanni re je 104.7 FM eleyii ti won bere si gbe ohun safefe lai gbase, ti ijoba si ti siwon lowo ise ninu osu ke...
Read More
Oloye Olusegun Obasanjo Pelu Aare Muhammadu Buhari Lodun 1978

Oloye Olusegun Obasanjo Pelu Aare Muhammadu Buhari Lodun 1978

Igba kan lo, igba kan bo. Igba kan o si lo bi orere. Awon mejeeji ti jo se olori Nigeria gege bi ijoba ologun ati alagbada.
Read More