Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu Malaysia ...
Read More
Home / Yoruba
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts

"Oserekurin Ti Mo Fe Lati Je Ete Re Ni...": Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran Lati Kiisi?
Bimbo Thomas Ti a ba n so nipa ise tiata ile Naijeria, Bimbo Thomas ti kuro ni ojewewe ti won nawo juwe re. Lara awon fiimu to ti k...
Read More

Akojopo Awon Leta Morufa Eko Lati Ikinni De Ipari (1-14)
Itan leta Morufa Eko ti dori eleekejila, fun irorun awon eniyan ti ko ti ri awon kan tabi meji ka ninu awon leta Morufa, a ti pese ona aba...
Read More
Aja Je Omo Tuntun Niluu Asaba: Abiyamo Padanu Omo Re Kan Soso Sinu Agbara Eje
Isele kan to sele lojo Eti to koja yii ni Asaba to wa ni Ipinle Delta je eyi to ba ni lokan je jina. Arabirin kan, eni odun metadinlogoj...
Read More
Won Ri Igbo Lapo Eegun To Ji Egberun Metadinlogota Owo Naira: Awon Olopaa Ti Mu Ara Orun To N Fagbo To Tun Jale
Awon Eegun kan ni owo awon olopa ti te leyin ti won ja ero olokada kan lole owo to to bi egberun metadinlogota (57K) niluu Nsukka Igb...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)