Smiley face
Fayose tí ń kọ gómìnà tuntun niṣe lai tí wọlé

Fayose tí ń kọ gómìnà tuntun niṣe lai tí wọlé

Fayose tí ń kọ Eleka niṣe. Eleka to  jẹ igbakeji Fayose àti ẹni tí Fayose fà kalẹ láti gba ipò rẹ gẹ́gẹ́ bí gómìnà tuntun náà tí ń kó bí wọn...
Read More
Omoyele Sowore yọjú sì Aláàfin Ọ̀yọ́

Omoyele Sowore yọjú sì Aláàfin Ọ̀yọ́

Aláàfin ń bínú wọn lọ rèé bọ'Fa. Tí'Fá bá fọre tí Lamide bá ni kò rí bẹ́ẹ̀ ńkọ́? Ojú ire Lamidi lẹbọ, ẹyọnu Lamidi lètùtù. Ẹ má bá L...
Read More
Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LASU

Gani Adams náà tí kàwé gboyè ni LASU

Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfo Ilẹ̀ Yorùbá, Iba Gani Abiodun Ige Adams náà tí padà kàwé gboyè ni ile ẹ̀kọ́ Yunifásítì. Ṣebi àwọn Yorùbá lóní imọ kò pín s...
Read More