Ìwé ìròyìn Financial Times tilu London tàbùkù Buhari Olayemi Oniroyin 3/08/2019 11:29:00 pm Add Comment Edit Ìwé ìròyìn Financial Times tilu London tí toju onika mẹsan an kaa pelu bi won se gbe e jade nínú ìwé ìròyìn wọn wí pé, Aare Muhammadu Buhari... Read More
Ìdí ti ọga ọlọ́pàá fi pe Sàràkí lẹẹkan síi lórí idigunjale Ọfa - Amofin Olabimtan Olayemi Oniroyin 7/28/2018 02:27:00 pm Add Comment Edit Àwọn onwoye nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú tí ṣàlàyé wí pé, kò yẹ kó jẹ ohun ijoloju wí pé oga àgbá àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ yìí tún padà pe Bukola Sàràkí lórí ... Read More
Sàràkí lè dá Buhari lágbo nu Olayemi Oniroyin 7/23/2018 11:10:00 pm Add Comment Edit Inúfu-àyàfu ni ẹgbẹ́ òṣèlú APC wá báyìí pelu ahesọ ọ̀rọ̀ tí ń lọ kiri wí pé, Ààrẹ ilé igbimo asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí kò ní pẹ fi ẹg... Read More
Ìkà tí ẹbi Abiola ṣe fún MKO ju ti IBB àti Abacha lọ Olayemi Oniroyin 6/18/2018 09:43:00 pm Add Comment Edit Ìròyìn tí kárí ayé wí pé wọn ti fi olóògbé Moshood Kashimawo Olawale Abiola jẹ òye idanilọla orile-ede Nàìjíríà tó gaju lọ, GCFR. Ṣùgbọ́n ẹ... Read More
Wọn tí yọ orúkọ Bukola Sàràkí kúrò nínú ẹsun idigunjale tó wáyé l'Ọffa Olayemi Oniroyin 6/17/2018 03:57:00 pm Add Comment Edit Àṣírí tí lu jáde báyìí wí pé wọn ti fà orúkọ Bukola Sàràkí kúrò nínú esun ìdaràn idigunjale tó wáyé nílùú Ọffa níbi tí àìmọye èmi ti ṣòfò. ... Read More