YATTYNANA |
Sebi awon Yoruba loni ti ina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Ojo to si n ro lowo ti ko ti i da, Edumare nikan lo moye eniyan to ku tojo yoo pa.
Awon Yoruba kan naa lo tun so wi pe oro okeere, ti ko ba lekan dandan ni ko din. Ohun ti ko si ye enikan kedere ni niwaju Olorun oba oke.
Yatty, okan lara awon omo Ayefele meta to sa leyin MON ni ilu Amerika, to tun je eyi to gbajugbaja julo se ojo ibi re lana ode yii.
Bi o tile je wi pe pupo ninu awon ololufe Yatty ni won fi aidunnu won han pelu ohun ti Yatty se (eleyii ti ko ti so idi pataki to fi se ohun to se si oga re) sibesibe, gbogbo eniyan ni won n ki ku ori ire ojo ibi re to ko layo.
Yatta naa si jade sori ero Facebook re pelu awon aworan re tuntun ati awon akole orisiirisii eleyii to fi n dasa gege bi ise re.
![]() |
'GBAGBE OSHI' |
Lara awon akole ti Yatty ju sori afefe naa ni: "IGBA EDA ASIKO EDA WA LOWO BABA OKE". 'GBAGBE OSHI', "HBD YATTYNANA" at "AM A WINNER" .
Awon ololufe Yatty naa si beeri si ni i ki ni mesan-mewa lairo ti asemase re rara.
Orisiirisii oro lo ti n lo nigboro bayii. Awon kan ni boya Yinka Ayefele ni ko toju won to. Awon kan ni Yatty ati awon meji toku fe maa je ju oni nnkan lo ni. Opolopo lo si n ro ohun ti yoo je igbeyin Yatty pelu igbese re.
Awon 'Aja' Ayefele ti wa ni ilu Amerika ti won wa Yatty ati awon meji yoku. Isesi Yatty ko si dabi eni eru n ba rara leyin asemase yii.
Ojo to n ro lowo ni oro yii, enikeni ko le so iye eni ti yoo pa. The end Lopin sinima. Olayemi Oniroyin lopin alaye gbogbo.
E ku ikale
badddooooooooooo
ReplyDeletewetin now be the guy plan, him want start his own band or wetin? anyway, i wish him best of uck
ReplyDeleteOhun to pamo oju Olorun nikan lo to ki enikeni ma dajo. period
ReplyDeleteOmo gbagbe oshi. opportunity comes but once. but make sure say dem no catch u
ReplyDeleteIgba eda asiko eda wa lowo Olorun. baba mimo je ki asiko temi naa de.
ReplyDeleteIgba eda asiko eda wa lowo Olorun. baba mimo je ki asiko temi naa de.
ReplyDeletewetin now be the guy plan, him want start his own band or wetin? anyway, i wish him best of luck Ǻn̶̲̥̅̊ԃ Tobilorigangan is here 4 u, wen u need talkind Drummer, let me kno.