Oba Eko Lo Fun L'Oluomo |
Mike Fash setan lati gbe Oba Fuji K1 wo ilu Amerika pelu ariwo to mile titi.
Osu kokanla titi wo osu kejila odun yii ni Orbit Entertaiment setan lati te pepe faaji pelu Arabambi Osomo 1.
Bi Kwam1 se n sere ni Chicago bee ni yoo ma pate alujo ni Dallas, awon New York gan ko ni gba fun de-Ultimate ko lo lai maa fi orin salaye oro fun won.
Wasiu Ayinde maa duro sere ni Brooklyn ati Houston. Maryland gan maa gbalejo Oluomo of Lagos.
Olayemi Oniroyin, bo se n sele ni mo n tele ni gbigbona. Ko tutu mo mi lowo ri.
#Gba sibe.
E Ba Mike Fash Soro Nibi Fun Alaye Lekunrere
America O Te Yii oo |
E Ba Mike Fash Soro Nibi Fun Alaye Lekunrere
Orbit Ent- 718.415.3361
Orbit Ent- 718.415.3361
We can't wait to see the king of fuji. K1 nooni
ReplyDeleteK1 lojulowo oba fuji. mo feran orin re gan-an. ayo ati laaafia lo mo lo. ki Olorun pa alo ati abo gbogbo wa mo oo
ReplyDelete