Smiley face

Ile Jo, Dukia Sofo Ni Ilu Eko


Ina nla kan lo seyo ni idaji ana ni Great Nigeria House to wa ni erekusu Ipinle Eko.

Titi di igba yii, enikeni ko le so ohun to fa isele ijamba ina naa. Bi o tile je wi pe enikeni ko ba isele naa lo sugbon aimoye eniyan ni won fara pa nigba ti oke aimoye dukia jona wuruwuru ninu isele naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment