Owo awon olopa ti te awon igara olosa adigunjale mii ti won n da awon eniyan Ipinle Eko loro.
Olori egbe adigunjale naa ti oruko re n je Olubaba eleyii ti iwadii fi ye awon olopa olotelemuye wi pe o ti fi igba kan je omo ikose adigunjale leyin Abiodun Ogunjobi ti inagije re n je Godogodo.
Godogodo ti o je ogbologbo adigunjale ni owo awon olopa ti te ni nnkan bi osu melo kan seyin ni ile re to wa ni ijoba ibile Egbeda ni Ilu Ibadan.
Aimoye ohun ija oloro ni won gba lowo Olubaba ati awon emewa re.

0 comments:
Post a Comment