Smiley face

Baba Awon Omo Ibeta Ti Sakuro Nile Nitori Bukata

Nikete ti ogbeni Adewale Omole gbo wi pe iyawo re, Abosede Omole bi ibeta lo ti salo ti enikeni ko si mo ibi to wa bayii.

Ni Ipinle Ekiti ni iroyin ti kan wa nipa okunrin ti n se ise birikila (bricklayer), Adewale to sa kuro nile latari iberu bukata awon omo meta to wa saye leekan soso leyin awon omo meji ti won ti bi kale tele.

Gege bi iyawo re, Abosede Omole to bimo si Ekiti State University Teaching Hospital (EKSUTH) se so. Oni saaju ki oun to bimo, ti oun ti lo se ayewo oyun inu oun ti awon dokita si ti jeri wi pe omo meta ni oun gbe sikun ni oko oun ti bere si ni yo owokowo ninu ile.

Oni eyi to wa se keyin yii lo fi de gbogbo re lade.

Oko ti salo kuro nile nitori bukata omo tuntun meta.

Awon eniyan ni won n dawo fun arabirin yii bayii lati le fi se itoju ebun omo meta ti Oba Oluwa fi da ebi re lola. Iyawo si ti n be oko re ko dakun pada wale wa se itoju awon eje orun meta naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment