Agbara ti ejo ni, inu enu lo fi si.
Akeeke lo fi tie siru. Agbara Tatyana Kozhevnikovam to je omo ilu Russia
inu nnkan omobirin re lo wa.
Tatyana
ti jewo eleyii pelu bi o se fi oju ara re gbe nnkan alagbara eleyii ti o
mu iwe akosile Guiness Book of Record fun ni ami eye "World Record for
'vagina weightlifting'".
E ri wi pe eleyii tun ga ju.
0 comments:
Post a Comment