Smiley face

Èmi Kì í Ṣe Ajani 'Ó Le Kú'

Èmi Kì í Ṣe Ajani 'Ó Le Kú' 
Emi ki i se Ajani 'O Le Ku'.

'O Le Ku' ìfẹ́ ojú kòkòrò.
Àtẹnujẹ ló pa Súlé Ìgbìrà.
Àyà-aní-jù ló pa ọmọ Ọjẹdokun.

Ojukokoro lo seku p'Ajani ọkọ gbogbo ọmọge?

Ololufẹ tún mí wò.
Eniyan to ba dalẹ̀ ìfẹ́,
Bi eni talẹ̀ òòṣà ni.
Ta wa ni kò mọ̀ ìgbẹ̀yìn Baba Wande 'T'OLuwa Nile'?

Oju kan lada ni.
To ba di meji adohun ti won mu roju ogun.
Ọ̀rọ̀ ogun kì í rọ̀, ọ̀rọ̀ kì í gun régé.

Ifẹ mi kì í ṣe ìfẹ́ Ajani, ifẹ ẹ̀tàn
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment