Smiley face

Ife Si Maa Dun Bi Oyin- Foluke Daramola

 
Ana ode yii ni igbeyawo tuntun Foluke Daramola pe odun kan. Ana yii kan naa (February 15) ni ojo ibi re.

Foluke Daramola ko se ayeye ojo ayo meji yii, sugbon alaye re ni wi pe oun ati oko oun jo gbadun akoko naa papo daada.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment