Sebi awon Yoruba loni ori ti o gbeni ni i gbe alawo ire koni. Arakunrin Abiodun Oladeji eni ti gbogbo ebi re ti ko sile latari aisan jejere enu (cancer of the mouth) ti n da laamu ti se alabapada Gomina Olusegun Mimiko.
Aanu okunrin yii se Gomina gidigidi eleyii to mu fi owo re se ayewo enu okunrin ti awon eniyan ko tile le sun mo debi wi pe won yoo fi owo kan lenu.
Gomina ti fa okunrin naa fun komisanna fun eto ilera Ipinle Ondo bayii, a si gbo wi pe o ti wa ni Obafemi Awolowo University Teaching Hospital to wa ni Ile Ife fun itoju ni kiakia.
 
 
 
 



0 comments:
Post a Comment