Awon omo onijo Samba gba gbogbo oju popona ilu Sao Paulo nibi isidi ajodun to maa n waye ni ilu naa ti odun 2014. Gege bi iroyin se so fun wa, awon onworan bi egberun lona ogbon (30,000) ni won tu yaaya lati wa wo orisiirisii ibadi okoto ti n ta rain-in rain-in eleyii ti awon omoge ti won je oju ni gbese pate re fun won.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment