Ogangan oju oja ero ni ado oloro awon Boko Haram ti bu gbamu ni ilu Maiduguri nibi ti awon eniyan bi aadota ti se agbako iku ijiji.
Pupo awon eniyan ti iku pa yii ni won je awon omode.
Ninu Ijamba buruku to waye lojo Abameta to koja yii loju oja ti ko jina si papako ofurufu ilu naa ni ado oloro kan ti koko bu gbamu lojiji, nibi awon eniyan ti n sa asala fun emi won ati bi awon kan se n tiraka ati gba awon kan la lowo iku ni ado mii naa tun dun laaarin iseju okan ti alakoko dun eleyii to se afikun awon eniyan ti won ba isele naa lo nigba ti aimoye farapa.

0 comments:
Post a Comment