Smiley face

Ayeye Ojo Ibi Oba Fuji Ni Ijebu Ode


K1 de Ultimate se ayeye ojo ibi re lana ninu ile nla re, Ule Ojusagbola Masion to wa ni Ijebu Ode. Atorise korin, St. Janet naa lulu korin to gbamuse fun oba fuji. Inu Ayinde omo Anifowose dun, bi Arabambi se n na naira ni nawo dollar.


Igba odun, odun kan fun Olu Omo of Lagos.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment