Sebi bi igba eda ba de, bi ologbon ni i jo loju araye. Ise orin ti dowo, owo nla fun eni to ba rise aje se. Bi D-one ko tile morin ko, agbateru ise orin ati igbohunsafefe ni ise re, Edumare si ti fi alubarika si i. Ko si iru moto ti omo Adeneye ko ni lagbala. Hummer ati Bentley wa nibi to daso bo mo lagbala ti o reni gun, joojumo ni relu oba pada wale bi eni lo si Shomolu. Igba yii to n dun ko ni tan, ire ayo fun gbogbo eni n woju Oluwa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment