Kosi ibi ti K1 ko nile si, bo se ni ile ni ilu Amerika ni awon eniyan
tun beri fun ile re to wa ni Canada, eyi to wa Ni Eko koja meji. Sugbon
eyi ti Arabanbi ko si Liworo Avenue, GRA, Ijebu Ode ni Ipinle Ogun tun
koja afenuroyin. A si gbo wi pe ile tuntun yii ni aafin oba Fuji wa
bayii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment