Smiley face

"E Yee Wahala Mi Mo. Se Emi Ni Mo Ji Omo Yin Ni Abi Emi Ni Boko Haram Ti Ju Bombu?" - Jonathan

Aare Goodluck Jonathan ti so seti gbogbo awon omo Naijeria wi pe ki awon ara ilu ye e gbogun ti oun mo nipa oro awon omobirin bi igba (200) ti Boko Haram jigbe salo.

O ni kaka bee Boko Haram lo ye ki awon omo Naijeria o doju ifehonuhan ati fitinati won ko kii se oko Patience rara.



Oro yii lo so lati enu igbakeji Minisita ilu Abuja, Arabirin Olajumoke Akinjide.

Awon oro yii lo jade nibamu pelu iwode ipolongo #BringBackOurGirls eleyii ti minisita fun eto eko nigba ri, Oby Ezekwezili saaju won lati yawo Aso Rock l'Abuja. Sugbon ti awon godogodo oloju pipon bi ti Sango da won pada bi owo Baba Ijebu ki won to sunmo regberegbe ile ijoba.

Aare tun so wi pe awon eniyan n fun oun ni oruko orisiirisii bi "Broda Suegbe"," Broda Rindinrindin" Broda Slow-slow latari wi pe oun ko jafafa lati se awari awon omo ti eye asa awon Boko Haram jigbe ni Chibok. Aare fi ye gbogbe eniyan wi pe adiye oun laagun o, iye ni o je ka mo.

E je ka gbo die ninu oro Aare ile Nigeria:

"It is wrong and most unfair to suggest that there was a slow reaction to this kidnapping.

As Commander-in-Chief, Mr. President meets with the security chiefs almost daily and he is on constant consultation with regional and global partners on this terrorists' threat.
"We must be careful not to politicise the campaign against terrorism.

When a bomb goes off in Kabul, Afghanistan, the people of Afghanistan do not blame the government, they blame the terrorists.

"When a bomb goes off in Bagdad, Iraq, the people of Iraq do not blame the government, they blame the terrorists.

"When a bomb goes off in Islamabad, Pakistan, the people of Pakistan do not blame the government, they blame the terrorists.

"When a bomb goes off in Nigeria, we must all unite to fight the terrorists."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

7 comments:

  1. Ti oro nigeria basu e fi ori oye to wa sile
    Ko ma lo .

    ReplyDelete
  2. Olorun nikan lo le saanu fun wa Nigeria. The 'sharing' of innocent blood is much. Chai! Diariz God ooo

    ReplyDelete
  3. Awon Soja ti Amerika ran wa gan o ti su won nitori awon ijooba wa ko lati se ohhun to ye kan se. o dabi eni wi pe ijoba ggan lowa nidi Boko Haram.Eni ki awon soja o maa doju ko iku, e ko se itoju won. Irinse ti awon boko haram n lo gan soja nigeria ko ji. joojumo ni nigeria fi eje we, awon olori kosi kobi rara si. kaka bee, ipolongo idibo ni won baa ka. aye won maa baje ni

    ReplyDelete
  4. Oluwa shanu wa ni ori lede nigeria iwo la fe kio wa ran wa lowo ijoba ko le da nkankan se lai si atileyin re, oluwa gba wa oooo

    ReplyDelete
  5. Egbomi o, nje o leto fun ijoba tonife ara ile re lati so pe ki awon ara ilu gbada odo awon boko haram lo lati lo fi eronu han, kini Aare je olori alabo (Commander in Chief of armed forces) fun nigba ti kilo pese abo toto fun awon ara ilu. Oro amonran mi si Aare ni wipe, tiko baa ye o mon, kowe fi ipo sile.

    ReplyDelete
  6. E se gan-an fun awon iriwisi ati idasi yin. Olorun naa ni a maa kepe lati ba tu Naijeria se. Osuka nla ko reru agba. Olorun yoo ran wa lowo. Amin. E se leekan si.

    ReplyDelete