Eni wu Eledumare ni i gbe ga, igba eda si wa lowo Baba oke. Ilu Amerika ni Khabirat Kafidipe wa lowolowo bayii nibi to ti n fi eja tutu mu tea gbigbona oniwara funfun.
Iroyin ta a gbo ni wi pe oserebirin yii ko ni pe dari de silu Naijeria lati wa bere eto ori Telifisan tuntun kan ti akole re n je KAFIOMOGE.
Eto KAFIOMOGE yii lagbo wi pe yoo da lori oge sise eleyii ti yoo maa fi ede Yoruba to gbamuse gbe kale. Ile ise Tunde Kelani (Mainframe/OPOMULEROTV) naa ni o maa se agbateru eto tuntun naa.
E ku oju lona!
<<<
Olayemi maa wo omo yii bo se pon bi moinmoin olororo, awo re tutu minijojo bi eja aro inu odo, oju re wa mole kedere bi omo tuntun jojolo. Chai! Chai!! Chai!!! Diariz God ooooo
#DoroKaffy
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment