Ado oloro iku kan ni awon onise bi kan ti won fura si gege bi Boko Haram gbin sinu ile iwe Kano School of Health Technology eleyii to wa loju ona Gida Murtal. Ado oloro yii lodun losan oni yii nibi aye igboko si eleyii ti ko jina si ofiisi oga agba ile iwe naa. Aimoye eniyan loku nibi isele naa eleyii ti enikeni ko ti le so pato bayii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment