Smiley face

KILODE TI AWON OLOPA FI ASO DE OJU BOKO HARAM TI WON MU NI ILU KANO?

Owo awon olopa ilu Kano ti te afurasi kan ti won lo wa lara awon to ju ado oloro to dun ninu ogba ile iwe Kano State School of Hygiene losan oni (23/06/14).
Komisanna awon olopa ti ilu Kano, Ogbeni Adenrele ti jeri si isele naa.



E  je ka gbo ohun ti won so;

"The suspect is in our custody, and the vehicle he used for the operation has also been towed to the police headquarters.

"We will get to know the motive behind the attack, and who sent him on this deadly errand."

"There was an explosion in the school this afternoon and it happened right inside the school premises. That is why we had to move in.

I want to confirm to you that 20 people were moved to the hospital, but eight were confirmed dead and 12 others injured."


Sugbon ohun to jo ni loju ni bi awon olopa se fi aso funfun de okunrin naa loju eleyii ti a ko le so idi pataki ti won fi se bee.


Abi eyin le so fun wa?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment