Gege bi oro Oba orin, Osupa, agba olorin yii gba wi pe bakan meji loro eda laye bi ode to lo si inu igbo lo pa eran. O ni ode le ri eran pa, o si seese ko pada lowo ofo. Bakan meji ni. Ti oserebirin onitia ba n dun nu wi pe yigi oun ko baje, e je ka ba a dupe nitori bakan meji ni.
Toyin AIMAKHU aya Johnson fi joojumo dupe lowo Oluwa oba fun adun igbeyawo.
0 comments:
Post a Comment