Smiley face

Omo Oga Bello Se Igbeyawo Alarinrin Ni Ilu Eko

Oga Bello sin omobirin re, Omolara lo si ile oko ni ojo Abameta to koja yii ni ilu Eko. Igbeyawo alarinrin yii waye ninu gbongan nla Bluroof to wa ninu ogba LTV .

Leyin ayeye naa, Ogbeni Moshoodi Agboola Bolarin lo mu Omolara lo sile gege bi alarede tuntun. Aimoye irawo osere ni won peju-pese sibi ojo ayo naa. Adura wa si ni wi pe ki Oba Oke ba wa fi adun igbeyawo si aarin toko-taya tuntun..

Maa ma se afikun awon aworan to ku nikete to ba te mi lowo.

#RamadanKareem fun awon Musulumi ododo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment