Ohun to daju ni wi pe Aare Goodluck Jonathan ilu Nigeria feran aso dandoogo ilu re to maa n wo kiri.
Sugbon
losan oni yii ni ilu Amerika, nibi ipade pataki kan ti n lo lowo, Aare
paso da pelu kootu dudu to gbamuse, awotele buluu eleyii to laju daada
bi funfun pelu tai olomi buluu to reju bi igba to je wi pe alaro to re
tai naa gbagbe re sinu omi ni Aare ko sorun.
Akiyesi
aworan si fi han wi pe Aare sese ge irun ori re ni eleyii to mu oju re
tutu bi omoluabi eniyan. Bi Aare se n rerin to n ba awon eniyan lowo ni
ehin enu re n sana bi igba eniyan polowo close-up ose ifohin.
0 comments:
Post a Comment