Gomina Ipinle Osun nigba kan ri, Omo'ba Olagunsoye Oyinlola ti tewo gba igbale lonii ni ilu Oshogbo niwaju awon olori egbe APC.
Lara awon eniyan to peju-pese sibe ni Gomina Ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola, Ibikunle Amosun, Bisi Akande, Bukola Saraki ati awon eniyan jankanjankan lagbo oselu.
0 comments:
Post a Comment