Fun awon to je ololufe Gomina Rauf Aregbesola, ilu Oshogbo
dun lonii [5-8-14] bi igba eniyan gun eja ati eran ti won fi maggi bo
daada ninu odo, eleyii ti won pada din ninu ororo, ti won wa ko si aarin
buredi fun jije.
Omidan Omokehinde to je okan lara
awon ololufe Olayemi Oniroyin wa ni gbagede ti awon agba oloselu lati
inu Egbe APC ti ki Omo'ba Olagunsoye Oyinlola kaabo sinu Egbe Onigbale.
Gege
bi ero Kehinde, oni idarapo Oyinlola ninu egbe APC ti mu okiki gomina
Rauf Aregbe lekenka eleyii to fun ni idaniloju wi pe lojo kesan-an osu
kejo odun yii, egbe onigbale ni o leke.
0 comments:
Post a Comment