Àwọn ènìyàn ta padà nígbà tá ń gòkè, le pada wúlò ta bá ń sòkalẹ̀ bọ̀ Olayemi Oniroyin 12/20/2017 08:58:00 am Add Comment Edit Má gbegbe awon olóore rẹ nígbà tó kéré. Ma seranti awon eniyan ti won dúró tì ọ nígbà tí kò sì ohunkóhun lọ́wọ́ rẹ nígbà to ba gòkè. Awon Y... Read More
Ni Ìpínlẹ̀ Anambra, awon omo ileewe tí wọ́n ṣe dáadáa ní kíláàsì gba ẹ̀bùn ewúré Olayemi Oniroyin 12/19/2017 04:31:00 pm Add Comment Edit Ni Ìpínlẹ̀ Anambra, awon omo ileewe tí wọ́n ṣe dáadáa ní kíláàsì gba ẹ̀bùn ewúré Kérésìmesì tí dùn Read More
Ìdí pàtàkì tí ẹ̀bùn ọdún fi ṣe pàtàkì Olayemi Oniroyin 12/19/2017 01:20:00 pm Add Comment Edit Ìkéde pàtàkì fún àwọn ènìyàn pàtàkì tí wọ́n rí ÌDÍ pàtàkì tí ìkéde yìí fi jẹ́ pàtàkì. Àwọn ènìyàn pàtàkì tí rí ìdí pàtàkì láti fún ara wọn... Read More
Má rọra, iro láyé; òtítọ́ kò sí níbikíbi Olayemi Oniroyin 12/18/2017 03:38:00 pm Add Comment Edit Lọ́jọ́ tí Buhari ṣe ọjọ́ ìbí, àìmọye gomina ni won peju sile àgbàrá Abuja. Won ki Buhari tẹrin-tẹyẹ. Awon kan tilẹ ń kí ni oriki ìdílé tí B... Read More
Tí ọmọdé bá ṣubú... Olayemi Oniroyin 12/13/2017 07:26:00 pm Add Comment Edit MoẸyin ènìyàn mi, máa bẹ yín láti fi òye gidi gbé àlàyé mi. Nítorí yóò tako ohun tẹ̀ẹ́ mọ tàbí ìgbàgbọ́ yin. Ti ọmọ iya méjì bá wo yèwù, t... Read More